-
2 Kíróníkà 19:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Jéhù+ ọmọ Hánáánì+ aríran jáde lọ bá Ọba Jèhóṣáfátì, ó sì sọ fún un pé: “Ṣé èèyàn burúkú ló yẹ kí o máa ràn lọ́wọ́,+ ṣé àwọn tó kórìíra Jèhófà ló sì yẹ kí o nífẹ̀ẹ́?+ Nítorí èyí, ìbínú Jèhófà ru sí ọ. 3 Síbẹ̀, àwọn ohun rere kan wà tí a rí nínú rẹ,+ nítorí o ti mú àwọn òpó òrìṣà* kúrò ní ilẹ̀ yìí, o sì ti múra ọkàn rẹ sílẹ̀* láti wá Ọlọ́run tòótọ́.”+
-