2 Kíróníkà 29:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Bákan náà, ọ̀pọ̀ ẹbọ sísun ló wà,+ títí kan àwọn ibi tó lọ́ràá lára àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ àti àwọn ọrẹ ohun mímu fún àwọn ẹbọ sísun.+ Bí wọ́n ṣe mú iṣẹ́ ìsìn ilé Jèhófà pa dà bọ̀ sípò* nìyẹn.
35 Bákan náà, ọ̀pọ̀ ẹbọ sísun ló wà,+ títí kan àwọn ibi tó lọ́ràá lára àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ àti àwọn ọrẹ ohun mímu fún àwọn ẹbọ sísun.+ Bí wọ́n ṣe mú iṣẹ́ ìsìn ilé Jèhófà pa dà bọ̀ sípò* nìyẹn.