2 Àwọn Ọba 19:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àìsáyà sì sọ fún wọn pé: “Ẹ sọ fún olúwa yín pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Má bẹ̀rù+ nítorí àwọn ọ̀rọ̀ tí o gbọ́, àwọn ọ̀rọ̀ tí àwọn ẹmẹ̀wà* ọba Ásíríà fi pẹ̀gàn mi.+
6 Àìsáyà sì sọ fún wọn pé: “Ẹ sọ fún olúwa yín pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Má bẹ̀rù+ nítorí àwọn ọ̀rọ̀ tí o gbọ́, àwọn ọ̀rọ̀ tí àwọn ẹmẹ̀wà* ọba Ásíríà fi pẹ̀gàn mi.+