-
Ẹ́sírà 5:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 A fẹ́ kí ọba mọ̀ pé a lọ sí ìpínlẹ̀* Júdà, ní ilé Ọlọ́run títóbi, wọ́n ń fi àwọn òkúta ńlá tí wọ́n ń yí sí àyè wọn kọ́ ilé náà, wọ́n sì ń to àwọn ẹ̀là gẹdú sí àwọn ògiri. Àwọn èèyàn náà ń fi ìtara ṣe iṣẹ́ náà, ìsapá wọn sì ń mú kó tẹ̀ síwájú.
-