ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 12:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Oṣù yìí ni yóò jẹ́ ìbẹ̀rẹ̀ àwọn oṣù fún yín. Òun ni yóò jẹ́ oṣù àkọ́kọ́ fún yín nínú ọdún.+

  • Ẹ́kísódù 12:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “‘Kí ẹ máa rántí ọjọ́ yìí, kí ẹ sì máa ṣe ayẹyẹ rẹ̀, kó jẹ́ àjọyọ̀ sí Jèhófà jálẹ̀ àwọn ìran yín. Ẹ máa pa àjọyọ̀ náà mọ́, ó ti di òfin fún yín títí láé.

  • Léfítíkù 23:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ìrọ̀lẹ́* ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìíní+ ni kí ẹ ṣe Ìrékọjá+ fún Jèhófà.

  • Diutarónómì 16:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 “Máa rántí oṣù Ábíbù,* kí o sì máa ṣe ayẹyẹ Ìrékọjá fún Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ torí pé oṣù Ábíbù ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ mú ọ kúrò ní Íjíbítì ní òru.+

  • Ẹ́sítà 3:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ní oṣù kìíní, ìyẹn oṣù Nísàn,* ọdún+ kejìlá Ọba Ahasuérúsì, wọ́n ṣẹ́ Púrì,+ (ìyẹn Kèké) níwájú Hámánì láti mọ ọjọ́ àti oṣù, ó sì bọ́ sí oṣù kejìlá, oṣù Ádárì.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́