Ẹ́sítà 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 ní ọdún kẹta ìjọba rẹ̀, ó se àsè ńlá fún gbogbo àwọn ìjòyè rẹ̀ àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. Àwọn ọmọ ogun Páṣíà+ àti Mídíà,+ àwọn èèyàn pàtàkì àti àwọn olórí ìpínlẹ̀* wà níwájú rẹ̀, Ẹ́sítà 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Wọ́n mú Ẹ́sítà lọ sọ́dọ̀ Ọba Ahasuérúsì ní ilé ọba ní oṣù kẹwàá, ìyẹn oṣù Tébétì,* ní ọdún keje+ ìjọba rẹ̀.
3 ní ọdún kẹta ìjọba rẹ̀, ó se àsè ńlá fún gbogbo àwọn ìjòyè rẹ̀ àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. Àwọn ọmọ ogun Páṣíà+ àti Mídíà,+ àwọn èèyàn pàtàkì àti àwọn olórí ìpínlẹ̀* wà níwájú rẹ̀,
16 Wọ́n mú Ẹ́sítà lọ sọ́dọ̀ Ọba Ahasuérúsì ní ilé ọba ní oṣù kẹwàá, ìyẹn oṣù Tébétì,* ní ọdún keje+ ìjọba rẹ̀.