Àìsáyà 21:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 A ti sọ ìran kan tó le fún mi: Ọ̀dàlẹ̀ ń dalẹ̀,Apanirun sì ń pani run. Gòkè lọ, ìwọ Élámù! Gbógun tini, ìwọ Mídíà!+ Màá fòpin sí gbogbo ẹ̀dùn ọkàn tó mú kó bá àwọn èèyàn.+ Jeremáyà 51:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Ẹ dán ọfà;+ ẹ gbé àwọn apata ribiti.* Jèhófà ti ru ẹ̀mí àwọn ọba Mídíà sókè,+Torí ó ní in lọ́kàn láti pa Bábílónì run. Nítorí ẹ̀san Jèhófà nìyí, ẹ̀san nítorí tẹ́ńpìlì rẹ̀. Dáníẹ́lì 5:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 “PÉRÉSÌ, a ti pín ìjọba rẹ, a sì ti fún àwọn ará Mídíà àti Páṣíà.”+
2 A ti sọ ìran kan tó le fún mi: Ọ̀dàlẹ̀ ń dalẹ̀,Apanirun sì ń pani run. Gòkè lọ, ìwọ Élámù! Gbógun tini, ìwọ Mídíà!+ Màá fòpin sí gbogbo ẹ̀dùn ọkàn tó mú kó bá àwọn èèyàn.+
11 “Ẹ dán ọfà;+ ẹ gbé àwọn apata ribiti.* Jèhófà ti ru ẹ̀mí àwọn ọba Mídíà sókè,+Torí ó ní in lọ́kàn láti pa Bábílónì run. Nítorí ẹ̀san Jèhófà nìyí, ẹ̀san nítorí tẹ́ńpìlì rẹ̀.