-
Ẹ́sírà 8:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Igba ó lé ogún (220) lára àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* wà, tí orúkọ gbogbo wọn wà lákọsílẹ̀. Dáfídì àti àwọn ìjòyè ló ní kí àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì máa ran àwọn ọmọ Léfì lọ́wọ́.
-