ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 9:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Àwọn tó ń gbé Gíbíónì+ náà gbọ́ ohun tí Jóṣúà ṣe sí Jẹ́ríkò+ àti Áì.+

  • Jóṣúà 9:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Àmọ́ ọjọ́ yẹn ni Jóṣúà sọ wọ́n di aṣẹ́gi àti àwọn tí á máa pọnmi fún àpéjọ náà+ àti pẹpẹ Jèhófà ní ibi tí Ó bá yàn,+ iṣẹ́ tí wọ́n sì ń ṣe títí di òní nìyẹn.+

  • Ẹ́sírà 2:43-54
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 43 Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* nìyí:+ àwọn ọmọ Síhà, àwọn ọmọ Hásúfà, àwọn ọmọ Tábáótì, 44 àwọn ọmọ Kérósì, àwọn ọmọ Síáhà, àwọn ọmọ Pádónì, 45 àwọn ọmọ Lébánà, àwọn ọmọ Hágábà, àwọn ọmọ Ákúbù, 46 àwọn ọmọ Hágábù, àwọn ọmọ Sálímáì, àwọn ọmọ Hánánì, 47 àwọn ọmọ Gídélì, àwọn ọmọ Gáhárì, àwọn ọmọ Reáyà, 48 àwọn ọmọ Résínì, àwọn ọmọ Nékódà, àwọn ọmọ Gásámù, 49 àwọn ọmọ Úúsà, àwọn ọmọ Páséà, àwọn ọmọ Bésáì, 50 àwọn ọmọ Ásínà, àwọn ọmọ Méúnímù, àwọn ọmọ Néfúsímù, 51 àwọn ọmọ Bákíbúkì, àwọn ọmọ Hákúfà, àwọn ọmọ Háhúrì, 52 àwọn ọmọ Básílútù, àwọn ọmọ Méhídà, àwọn ọmọ Háṣà, 53 àwọn ọmọ Bákósì, àwọn ọmọ Sísérà, àwọn ọmọ Téémà, 54 àwọn ọmọ Nesáyà àti àwọn ọmọ Hátífà.

  • Ẹ́sírà 2:70
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 70 Àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì, àwọn kan lára àwọn èèyàn náà, àwọn akọrin àti àwọn aṣọ́bodè pẹ̀lú àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* bẹ̀rẹ̀ sí í gbé inú àwọn ìlú wọn, gbogbo ọmọ Ísírẹ́lì yòókù* sì ń gbé inú àwọn ìlú wọn.+

  • Ẹ́sírà 8:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Igba ó lé ogún (220) lára àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* wà, tí orúkọ gbogbo wọn wà lákọsílẹ̀. Dáfídì àti àwọn ìjòyè ló ní kí àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì máa ran àwọn ọmọ Léfì lọ́wọ́.

  • Nehemáyà 7:73
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 73 Àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì, àwọn aṣọ́bodè, àwọn akọrin,+ àwọn kan lára àwọn èèyàn náà àti àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* pẹ̀lú gbogbo ọmọ Ísírẹ́lì yòókù* bẹ̀rẹ̀ sí í gbé inú àwọn ìlú wọn.+ Nígbà tó fi máa di oṣù keje,+ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ti wà nínú àwọn ìlú wọn.+

  • Nehemáyà 11:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Àwọn tó tẹ̀ lé e yìí ni àwọn olórí ìpínlẹ̀* tí wọ́n ń gbé ní Jerúsálẹ́mù. (Ìyókù àwọn tó wà ní Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì, àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ àti àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì,+ wọ́n ń gbé ní àwọn ìlú míì ní Júdà, kálukú sì ń gbé lórí ohun ìní rẹ̀ nínú ìlú rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́