Nọ́ńbà 3:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àwọn ọmọ Mérárì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn ni Máhílì+ àti Múṣì.+ Ìdílé àwọn ọmọ Léfì nìyí, gẹ́gẹ́ bí agbo ilé bàbá wọn.
20 Àwọn ọmọ Mérárì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn ni Máhílì+ àti Múṣì.+ Ìdílé àwọn ọmọ Léfì nìyí, gẹ́gẹ́ bí agbo ilé bàbá wọn.