Nehemáyà 8:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jéṣúà, Bánì, Ṣerebáyà,+ Jámínì, Ákúbù, Ṣábétáì, Hodáyà, Maaseáyà, Kélítà, Asaráyà, Jósábádì,+ Hánánì àti Pẹláyà, tí wọ́n jẹ́ ọmọ Léfì, ń ṣàlàyé Òfin náà fún àwọn èèyàn náà,+ orí ìdúró sì ni àwọn èèyàn náà wà. Nehemáyà 11:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 àti Ṣábétáì+ àti Jósábádì,+ látinú àwọn olórí àwọn ọmọ Léfì, tí wọ́n ń bójú tó àwọn iṣẹ́ míì tó jẹ mọ́ ilé Ọlọ́run tòótọ́
7 Jéṣúà, Bánì, Ṣerebáyà,+ Jámínì, Ákúbù, Ṣábétáì, Hodáyà, Maaseáyà, Kélítà, Asaráyà, Jósábádì,+ Hánánì àti Pẹláyà, tí wọ́n jẹ́ ọmọ Léfì, ń ṣàlàyé Òfin náà fún àwọn èèyàn náà,+ orí ìdúró sì ni àwọn èèyàn náà wà.
16 àti Ṣábétáì+ àti Jósábádì,+ látinú àwọn olórí àwọn ọmọ Léfì, tí wọ́n ń bójú tó àwọn iṣẹ́ míì tó jẹ mọ́ ilé Ọlọ́run tòótọ́