-
Ẹ́sírà 2:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 àwọn ọmọ Bébáì jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́fà ó lé mẹ́tàlélógún (623);
-
-
Ẹ́sírà 8:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àwọn olórí agbo ilé àti àkọsílẹ̀ orúkọ ìdílé àwọn tó tẹ̀ lé mi jáde kúrò ní Bábílónì nígbà ìjọba Ọba Atasásítà nìyí:+
-
-
Ẹ́sírà 8:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 látinú àwọn ọmọ Bébáì,+ Sekaráyà ọmọ Bébáì, ọkùnrin méjìdínlọ́gbọ̀n (28) sì wà pẹ̀lú rẹ̀;
-