Sáàmù 79:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 San án pa dà fún àwọn aládùúgbò wa ní ìlọ́po méje+Nítorí ẹ̀gàn tí wọ́n kó bá ọ, Jèhófà.+