Jeremáyà 12:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ohun tí Jèhófà sọ nípa gbogbo aládùúgbò mi burúkú, tí wọ́n ń fọwọ́ kan ogún tí mo fún àwọn èèyàn mi, Ísírẹ́lì nìyí:+ “Wò ó, màá fà wọ́n tu kúrò ní ilẹ̀ wọn,+ màá sì fa ilé Júdà tu kúrò ní àárín wọn.
14 Ohun tí Jèhófà sọ nípa gbogbo aládùúgbò mi burúkú, tí wọ́n ń fọwọ́ kan ogún tí mo fún àwọn èèyàn mi, Ísírẹ́lì nìyí:+ “Wò ó, màá fà wọ́n tu kúrò ní ilẹ̀ wọn,+ màá sì fa ilé Júdà tu kúrò ní àárín wọn.