-
Sáàmù 79:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 A ti di ẹni ẹ̀gàn lójú àwọn aládùúgbò wa;+
Àwọn tó yí wa ká ń fi wá ṣẹ̀sín, wọ́n sì ń fi wá ṣe yẹ̀yẹ́.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 25:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Kí o sọ nípa àwọn ọmọ Ámónì pé, ‘Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ. Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Torí ẹ sọ pé ‘Àháà!’ nígbà tí wọ́n sọ ibi mímọ́ mi di aláìmọ́, nígbà tí wọ́n sọ ilẹ̀ Ísírẹ́lì di ahoro àti nígbà tí ilé Júdà lọ sí ìgbèkùn,
-