-
Ìsíkíẹ́lì 36:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 torí náà, ẹ̀yin òkè Ísírẹ́lì, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ! Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ fún àwọn òkè ńlá àti àwọn òkè kéékèèké nìyí, fún àwọn ìṣàn omi àti àwọn àfonífojì, fún àwọn àwókù tó ti di ahoro+ àti fún àwọn ìlú tí wọ́n pa tì, tí àwọn tó là á já nínú àwọn orílẹ̀-èdè tó yí wọn ká ti kó ní ẹrù, tí wọ́n sì fi ṣe ẹlẹ́yà;+
-