-
Sáàmù 79:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 A ti di ẹni ẹ̀gàn lójú àwọn aládùúgbò wa;+
Àwọn tó yí wa ká ń fi wá ṣẹ̀sín, wọ́n sì ń fi wá ṣe yẹ̀yẹ́.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 34:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Àwọn orílẹ̀-èdè ò ní dọdẹ wọn mọ́, àwọn ẹran inú igbó ò ní pa wọ́n jẹ, ààbò yóò sì wà lórí wọn, ẹnì kankan ò sì ní dẹ́rù bà wọ́n.+
-