-
Jeremáyà 48:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Wọn ò yin Móábù mọ́.
Hẹ́ṣíbónì+ ni wọ́n ti gbèrò ìṣubú rẹ̀, pé:
‘Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a pa á run, kí ó má ṣe jẹ́ orílẹ̀-èdè mọ́.’
Kí ìwọ Mádíménì pẹ̀lú dákẹ́,
Torí idà ń tẹ̀ lé ọ.
-