Sáàmù 106:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 A ti dẹ́ṣẹ̀ bí àwọn baba ńlá wa;+A ti ṣe ohun tí kò dáa; a ti hùwà burúkú.+