Nehemáyà 9:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Àmọ́, àwọn baba ńlá wa kọjá àyè wọn,+ wọ́n sì ya alágídí,*+ wọn kò fetí sí àwọn àṣẹ rẹ. Sáàmù 78:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Wọn ò ní dà bí àwọn baba ńlá wọn,Ìran alágídí àti ọlọ̀tẹ̀,+Ìran tí ọkàn wọn ń ṣe ségesège*+Tí ẹ̀mí wọn ò sì jẹ́ olóòótọ́ sí Ọlọ́run.
8 Wọn ò ní dà bí àwọn baba ńlá wọn,Ìran alágídí àti ọlọ̀tẹ̀,+Ìran tí ọkàn wọn ń ṣe ségesège*+Tí ẹ̀mí wọn ò sì jẹ́ olóòótọ́ sí Ọlọ́run.