-
Nehemáyà 3:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Jóyádà ọmọ Páséà àti Méṣúlámù ọmọ Besodeáyà tún Ẹnubodè Ìlú Àtijọ́+ ṣe; wọ́n fi ẹ̀là gẹdú kọ́ ọ, wọ́n sì gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ sí i àti àwọn ìkọ́ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọ̀pá ìdábùú rẹ̀.
-