Nehemáyà 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jéṣúà bí Jóyákímù, Jóyákímù bí Élíáṣíbù,+ Élíáṣíbù sì bí Jóyádà.+ Nehemáyà 13:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ṣáájú àkókò yìí, Élíáṣíbù + tó jẹ́ ìbátan Tòbáyà+ ni àlùfáà tó ń bójú tó àwọn yàrá tí wọ́n ń kó nǹkan pa mọ́ sí* ní ilé* Ọlọ́run wa.+ Nehemáyà 13:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ọ̀kan lára àwọn ọmọkùnrin Jóyádà+ ọmọ Élíáṣíbù + àlùfáà àgbà ti di àna Sáńbálátì+ tó jẹ́ ará Hórónì. Torí náà, mo lé e kúrò lọ́dọ̀ mi.
4 Ṣáájú àkókò yìí, Élíáṣíbù + tó jẹ́ ìbátan Tòbáyà+ ni àlùfáà tó ń bójú tó àwọn yàrá tí wọ́n ń kó nǹkan pa mọ́ sí* ní ilé* Ọlọ́run wa.+
28 Ọ̀kan lára àwọn ọmọkùnrin Jóyádà+ ọmọ Élíáṣíbù + àlùfáà àgbà ti di àna Sáńbálátì+ tó jẹ́ ará Hórónì. Torí náà, mo lé e kúrò lọ́dọ̀ mi.