Nehemáyà 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Élíáṣíbù+ àlùfáà àgbà àti àwọn arákùnrin rẹ̀, àwọn àlùfáà, dìde láti kọ́ Ẹnubodè Àgùntàn.+ Wọ́n yà á sí mímọ́,+ wọ́n sì gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ nàró; wọ́n yà á sí mímọ́ títí dé Ilé Gogoro Méà+ àti títí dé Ilé Gogoro Hánánélì.+
3 Élíáṣíbù+ àlùfáà àgbà àti àwọn arákùnrin rẹ̀, àwọn àlùfáà, dìde láti kọ́ Ẹnubodè Àgùntàn.+ Wọ́n yà á sí mímọ́,+ wọ́n sì gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ nàró; wọ́n yà á sí mímọ́ títí dé Ilé Gogoro Méà+ àti títí dé Ilé Gogoro Hánánélì.+