Ẹ́sírà 10:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 látinú àwọn ọmọ Élámù,+ Matanáyà, Sekaráyà, Jéhíélì,+ Ábídì, Jérémótì àti Èlíjà; Ẹ́sírà 10:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Gbogbo àwọn yìí ni wọ́n fẹ́ àwọn aya àjèjì,+ wọ́n sì lé àwọn aya wọn lọ pẹ̀lú àwọn ọmọ wọn.+