ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 17:27-29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Gbàrà tí Dáfídì dé Máhánáímù, Ṣóbì ọmọkùnrin Náháṣì láti Rábà+ ti àwọn ọmọ Ámónì àti Mákírù+ ọmọkùnrin Ámíélì láti Lo-débà pẹ̀lú Básíláì+ ọmọ Gílíádì láti Rógélímù 28 kó ibùsùn wá, wọ́n tún kó bàsíà, ìkòkò, àlìkámà,* ọkà bálì, ìyẹ̀fun, àyangbẹ ọkà, ẹ̀wà pàkálà, ẹ̀wà lẹ́ńtìlì àti ẹ̀gbẹ ọkà wá, 29 wọ́n sì kó oyin, bọ́tà, àgùntàn àti wàrà wá.* Wọ́n kó gbogbo nǹkan yìí wá fún Dáfídì àti àwọn èèyàn tó wà pẹ̀lú rẹ̀ láti jẹ,+ torí wọ́n sọ pé: “Ebi ń pa àwọn èèyàn náà, ó ti rẹ̀ wọ́n, òùngbẹ sì ń gbẹ wọ́n ní aginjù.”+

  • 2 Sámúẹ́lì 19:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Ìgbà náà ni Básíláì+ ọmọ Gílíádì wá láti Rógélímù sí Jọ́dánì, kí ó lè sin ọba dé Jọ́dánì.

  • 1 Àwọn Ọba 2:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 “Àmọ́ kí o fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí àwọn ọmọ Básíláì+ ọmọ Gílíádì, kí wọ́n sì wà lára àwọn tí á máa jẹun lórí tábìlì rẹ, nítorí bí wọ́n ṣe dúró tì mí+ nìyẹn nígbà tí mo sá lọ nítorí Ábúsálómù+ ẹ̀gbọ́n rẹ.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́