-
Nehemáyà 8:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Nehemáyà tó jẹ́ gómìnà* nígbà yẹn, Ẹ́sírà + tó jẹ́ àlùfáà àti adàwékọ* pẹ̀lú àwọn ọmọ Léfì tí wọ́n ń kọ́ àwọn èèyàn sọ fún gbogbo àwọn èèyàn náà pé: “Ọjọ́ yìí jẹ́ mímọ́ lójú Jèhófà Ọlọ́run yín.+ Ẹ má ṣọ̀fọ̀, ẹ má sì sunkún.” Nítorí gbogbo àwọn èèyàn náà ń sunkún bí wọ́n ṣe gbọ́ ọ̀rọ̀ inú Òfin náà.
-