Ẹ́kísódù 28:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Kí o fi Úrímù àti Túmímù*+ sínú aṣọ ìgbàyà ìdájọ́ náà, kí wọ́n sì máa wà ní àyà Áárónì nígbà tó bá wá síwájú Jèhófà, kí Áárónì máa gbé ohun tí wọ́n fi ń ṣe ìdájọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí àyà rẹ̀ níwájú Jèhófà nígbà gbogbo. 1 Sámúẹ́lì 28:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Bí Sọ́ọ̀lù tilẹ̀ ń wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà,+ Jèhófà kò dá a lóhùn rárá, ì báà jẹ́ nípasẹ̀ àlá tàbí nípasẹ̀ Úrímù + tàbí àwọn wòlíì.
30 Kí o fi Úrímù àti Túmímù*+ sínú aṣọ ìgbàyà ìdájọ́ náà, kí wọ́n sì máa wà ní àyà Áárónì nígbà tó bá wá síwájú Jèhófà, kí Áárónì máa gbé ohun tí wọ́n fi ń ṣe ìdájọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí àyà rẹ̀ níwájú Jèhófà nígbà gbogbo.
6 Bí Sọ́ọ̀lù tilẹ̀ ń wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà,+ Jèhófà kò dá a lóhùn rárá, ì báà jẹ́ nípasẹ̀ àlá tàbí nípasẹ̀ Úrímù + tàbí àwọn wòlíì.