-
Nọ́ńbà 18:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Àkọ́pọ́n gbogbo ohun tó bá so nílẹ̀ wọn, tí wọ́n bá mú wá fún Jèhófà yóò di tìrẹ.+ Gbogbo ẹni tó mọ́ nínú ilé rẹ ló lè jẹ ẹ́.