2 Kíróníkà 27:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) ni Jótámù+ nígbà tó jọba, ọdún mẹ́rìndínlógún (16) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jérúṣà ọmọ Sádókù.+ 2 Kíróníkà 27:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó kọ́ ẹnubodè apá òkè ilé Jèhófà,+ ó kọ́ ohun púpọ̀ sórí ògiri Ófélì.+ Nehemáyà 3:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ tí wọ́n ń gbé ní Ófélì+ ṣe iṣẹ́ àtúnṣe títí dé iwájú Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn àti ilé gogoro tó yọ jáde náà.
27 Ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) ni Jótámù+ nígbà tó jọba, ọdún mẹ́rìndínlógún (16) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jérúṣà ọmọ Sádókù.+
26 Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ tí wọ́n ń gbé ní Ófélì+ ṣe iṣẹ́ àtúnṣe títí dé iwájú Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn àti ilé gogoro tó yọ jáde náà.