-
Nehemáyà 4:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Nígbà tí mo rí i pé ẹ̀rù ń bà wọ́n, ẹsẹ̀kẹsẹ̀ ni mo dìde, mo sì sọ fún àwọn èèyàn pàtàkì+ àti àwọn alábòójútó pẹ̀lú àwọn èèyàn yòókù pé: “Ẹ má bẹ̀rù wọn.+ Ẹ rántí Jèhófà, ẹni gíga tó yẹ ká máa bẹ̀rù;+ ẹ jà fún àwọn arákùnrin yín, àwọn ọmọkùnrin yín àti àwọn ọmọbìnrin yín pẹ̀lú àwọn ìyàwó yín àti ilé yín.”
-