-
1 Kíróníkà 25:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Síwájú sí i, Dáfídì àti àwọn olórí àwùjọ àwọn tó ń ṣiṣẹ́ ìsìn ya àwọn kan lára àwọn ọmọ Ásáfù, Hémánì àti Jédútúnì+ sọ́tọ̀ láti máa fi háàpù, àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín+ àti síńbálì*+ sọ tẹ́lẹ̀. Orúkọ àwọn tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn yìí ni, 2 látinú àwọn ọmọ Ásáfù: Sákúrì, Jósẹ́fù, Netanáyà àti Áṣárélà, àwọn ọmọ Ásáfù lábẹ́ ìdarí Ásáfù, ẹni tó ń sọ tẹ́lẹ̀ lábẹ́ àṣẹ ọba.
-