ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 31:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 “Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Jèhófà wí, “nígbà tí wọ́n á kọ́ ìlú+ fún Jèhófà láti Ilé Gogoro Hánánélì+ dé Ẹnubodè Igun.+

  • Sekaráyà 14:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Gbogbo ilẹ̀ náà láti Gébà+ dé Rímónì+ ní gúúsù Jerúsálẹ́mù yóò dà bí Árábà;+ yóò dìde, yóò sì máa gbé àyè rẹ̀,+ láti Ẹnubodè Bẹ́ńjámínì+ títí lọ dé ibi Ẹnubodè Àkọ́kọ́, títí lọ dé Ẹnubodè Igun àti láti Ilé Gogoro Hánánélì+ títí lọ dé àwọn ibi tí wọ́n ti ń fún wáìnì* tó jẹ́ ti ọba.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́