Nehemáyà 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Élíáṣíbù+ àlùfáà àgbà àti àwọn arákùnrin rẹ̀, àwọn àlùfáà, dìde láti kọ́ Ẹnubodè Àgùntàn.+ Wọ́n yà á sí mímọ́,+ wọ́n sì gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ nàró; wọ́n yà á sí mímọ́ títí dé Ilé Gogoro Méà+ àti títí dé Ilé Gogoro Hánánélì.+ Jeremáyà 31:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 “Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Jèhófà wí, “nígbà tí wọ́n á kọ́ ìlú+ fún Jèhófà láti Ilé Gogoro Hánánélì+ dé Ẹnubodè Igun.+
3 Élíáṣíbù+ àlùfáà àgbà àti àwọn arákùnrin rẹ̀, àwọn àlùfáà, dìde láti kọ́ Ẹnubodè Àgùntàn.+ Wọ́n yà á sí mímọ́,+ wọ́n sì gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ nàró; wọ́n yà á sí mímọ́ títí dé Ilé Gogoro Méà+ àti títí dé Ilé Gogoro Hánánélì.+
38 “Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Jèhófà wí, “nígbà tí wọ́n á kọ́ ìlú+ fún Jèhófà láti Ilé Gogoro Hánánélì+ dé Ẹnubodè Igun.+