ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 43:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ísírẹ́lì bàbá wọn wá sọ fún wọn pé: “Tọ́rọ̀ bá rí bẹ́ẹ̀, ohun tí ẹ máa ṣe nìyí: Ẹ kó àwọn ohun tó dáa jù ní ilẹ̀ yìí sínú àwọn àpò yín, kí ẹ gbé e lọ fún ọkùnrin náà bí ẹ̀bùn:+ básámù+ díẹ̀, oyin díẹ̀, gọ́ọ̀mù lábídánọ́mù, èèpo+ igi olóje, ẹ̀pà pítáṣíò àti álímọ́ńdì.

  • 1 Àwọn Ọba 10:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ó dé Jerúsálẹ́mù pẹ̀lú àwọn abọ́barìn* tó gbayì,+ pẹ̀lú àwọn ràkúnmí tó ru òróró básámù+ àti wúrà tó pọ̀ gan-an àti àwọn òkúta iyebíye. Ó lọ sọ́dọ̀ Sólómọ́nì, ó sì bá a sọ gbogbo ohun tó wà lọ́kàn rẹ̀.

  • 2 Àwọn Ọba 20:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Hẹsikáyà kí wọn káàbọ̀,* ó sì fi gbogbo ohun tó wà nínú ilé ìṣúra+ rẹ̀ hàn wọ́n, ìyẹn fàdákà, wúrà, òróró básámù àti àwọn òróró míì tó ṣeyebíye pẹ̀lú ilé tó ń kó ohun ìjà sí àti gbogbo ohun tó wà nínú àwọn ibi ìṣúra rẹ̀. Kò sí nǹkan tí Hẹsikáyà kò fi hàn wọ́n nínú ilé* rẹ̀ àti nínú gbogbo agbègbè tó wà lábẹ́ àkóso rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́