Jeremáyà 8:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ṣé kò sí básámù* ní Gílíádì+ ni? Àbí ṣé kò sí oníwòsàn* níbẹ̀ ni?+ Kí ló wá dé tí ara ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi kò fi tíì yá?+ Ìsíkíẹ́lì 27:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “‘“Júdà àti ilẹ̀ Ísírẹ́lì bá ọ dòwò pọ̀, wọ́n ń fi àlìkámà* Mínítì,+ àwọn oúnjẹ tó dára jù, oyin,+ òróró àti básámù+ ṣe pàṣípààrọ̀ ọjà lọ́dọ̀ rẹ.+
22 Ṣé kò sí básámù* ní Gílíádì+ ni? Àbí ṣé kò sí oníwòsàn* níbẹ̀ ni?+ Kí ló wá dé tí ara ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi kò fi tíì yá?+
17 “‘“Júdà àti ilẹ̀ Ísírẹ́lì bá ọ dòwò pọ̀, wọ́n ń fi àlìkámà* Mínítì,+ àwọn oúnjẹ tó dára jù, oyin,+ òróró àti básámù+ ṣe pàṣípààrọ̀ ọjà lọ́dọ̀ rẹ.+