Jeremáyà 8:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ṣé kò sí básámù* ní Gílíádì+ ni? Àbí ṣé kò sí oníwòsàn* níbẹ̀ ni?+ Kí ló wá dé tí ara ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi kò fi tíì yá?+
22 Ṣé kò sí básámù* ní Gílíádì+ ni? Àbí ṣé kò sí oníwòsàn* níbẹ̀ ni?+ Kí ló wá dé tí ara ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi kò fi tíì yá?+