Ẹ́sítà 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ọkùnrin Júù kan wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* Módékáì+ lorúkọ rẹ̀, ó jẹ́ ọmọ Jáírì, ọmọ Ṣíméì, ọmọ Kíṣì, ọmọ Bẹ́ńjámínì,+
5 Ọkùnrin Júù kan wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* Módékáì+ lorúkọ rẹ̀, ó jẹ́ ọmọ Jáírì, ọmọ Ṣíméì, ọmọ Kíṣì, ọmọ Bẹ́ńjámínì,+