Ẹ́sírà 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 (Ó wá látọ̀dọ̀ Réhúmù olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba àti Ṣímúṣáì akọ̀wé òfin àti àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn yòókù, àwọn adájọ́ àti àwọn gómìnà kéékèèké, àwọn akọ̀wé, àwọn èèyàn Érékì,+ àwọn ará Babilóníà, àwọn tó ń gbé ní Súsà,+ ìyẹn àwọn ọmọ Élámù+ Nehemáyà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ọ̀rọ̀ Nehemáyà*+ ọmọ Hakaláyà nìyí: Ní oṣù Kísíléfì,* ní ogún ọdún ìṣàkóso ọba,* mo wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá.* Ẹ́sítà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 lákòókò yẹn, Ọba Ahasuérúsì wà lórí ìtẹ́ rẹ̀ ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* Dáníẹ́lì 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Mo rí ìran náà, bí mo sì ṣe ń wò ó, mo wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* tó wà ní ìpínlẹ̀* Élámù;+ mo rí ìran náà, mo sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ipadò Úláì.
9 (Ó wá látọ̀dọ̀ Réhúmù olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba àti Ṣímúṣáì akọ̀wé òfin àti àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn yòókù, àwọn adájọ́ àti àwọn gómìnà kéékèèké, àwọn akọ̀wé, àwọn èèyàn Érékì,+ àwọn ará Babilóníà, àwọn tó ń gbé ní Súsà,+ ìyẹn àwọn ọmọ Élámù+
1 Ọ̀rọ̀ Nehemáyà*+ ọmọ Hakaláyà nìyí: Ní oṣù Kísíléfì,* ní ogún ọdún ìṣàkóso ọba,* mo wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá.*
2 Mo rí ìran náà, bí mo sì ṣe ń wò ó, mo wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* tó wà ní ìpínlẹ̀* Élámù;+ mo rí ìran náà, mo sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ipadò Úláì.