Jẹ́nẹ́sísì 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àwọn ọmọ Ṣémù ni Élámù,+ Áṣúrì,+ Ápákíṣádì,+ Lúdì àti Árámù.+ Àìsáyà 11:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà tún máa na ọwọ́ rẹ̀ lẹ́ẹ̀kejì, láti gba àṣẹ́kù àwọn èèyàn rẹ̀ pa dà, àwọn tó ṣẹ́ kù láti Ásíríà,+ Íjíbítì,+ Pátírọ́sì,+ Kúṣì,+ Élámù,+ Ṣínárì,* Hámátì àti àwọn erékùṣù òkun.+ Àìsáyà 21:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 A ti sọ ìran kan tó le fún mi: Ọ̀dàlẹ̀ ń dalẹ̀,Apanirun sì ń pani run. Gòkè lọ, ìwọ Élámù! Gbógun tini, ìwọ Mídíà!+ Màá fòpin sí gbogbo ẹ̀dùn ọkàn tó mú kó bá àwọn èèyàn.+
11 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà tún máa na ọwọ́ rẹ̀ lẹ́ẹ̀kejì, láti gba àṣẹ́kù àwọn èèyàn rẹ̀ pa dà, àwọn tó ṣẹ́ kù láti Ásíríà,+ Íjíbítì,+ Pátírọ́sì,+ Kúṣì,+ Élámù,+ Ṣínárì,* Hámátì àti àwọn erékùṣù òkun.+
2 A ti sọ ìran kan tó le fún mi: Ọ̀dàlẹ̀ ń dalẹ̀,Apanirun sì ń pani run. Gòkè lọ, ìwọ Élámù! Gbógun tini, ìwọ Mídíà!+ Màá fòpin sí gbogbo ẹ̀dùn ọkàn tó mú kó bá àwọn èèyàn.+