-
Jeremáyà 44:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Àwọn díẹ̀ ló máa bọ́ lọ́wọ́ idà, tí wọ́n á sì pa dà láti ilẹ̀ Íjíbítì sí ilẹ̀ Júdà.+ Lẹ́yìn náà, gbogbo àwọn tó ṣẹ́ kù nílẹ̀ Júdà, tí wọ́n wá sí ilẹ̀ Íjíbítì láti máa gbé ibẹ̀, máa mọ ẹni tí ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣẹ, bóyá tèmi ni tàbí tiwọn!”’”
-
-
Míkà 7:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n máa wá sọ́dọ̀ rẹ
-