Àìsáyà 49:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Wò ó! Màá gbé ọwọ́ mi sókè sí àwọn orílẹ̀-èdè,Màá sì gbé àmì* mi sókè sí àwọn èèyàn.+ Wọ́n máa fi ọwọ́ wọn gbé àwọn ọmọkùnrin rẹ wá,*Wọ́n sì máa gbé àwọn ọmọbìnrin rẹ sí èjìká wọn.+ Àìsáyà 62:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ kọjá, ẹ gba àwọn ẹnubodè kọjá. Ẹ tún ọ̀nà ṣe fún àwọn èèyàn.+ Ẹ ṣe ọ̀nà, ẹ ṣe òpópó. Ẹ ṣa òkúta kúrò níbẹ̀.+ Ẹ gbé àmì* sókè fún àwọn èèyàn.+
22 Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Wò ó! Màá gbé ọwọ́ mi sókè sí àwọn orílẹ̀-èdè,Màá sì gbé àmì* mi sókè sí àwọn èèyàn.+ Wọ́n máa fi ọwọ́ wọn gbé àwọn ọmọkùnrin rẹ wá,*Wọ́n sì máa gbé àwọn ọmọbìnrin rẹ sí èjìká wọn.+
10 Ẹ kọjá, ẹ gba àwọn ẹnubodè kọjá. Ẹ tún ọ̀nà ṣe fún àwọn èèyàn.+ Ẹ ṣe ọ̀nà, ẹ ṣe òpópó. Ẹ ṣa òkúta kúrò níbẹ̀.+ Ẹ gbé àmì* sókè fún àwọn èèyàn.+