Àìsáyà 40:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé: “Ẹ tún ọ̀nà Jèhófà ṣe!*+ Ẹ la ọ̀nà tó tọ́ + gba inú aṣálẹ̀ fún Ọlọ́run wa.+ Àìsáyà 48:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹ jáde kúrò ní Bábílónì!+Ẹ sá kúrò lọ́dọ̀ àwọn ará Kálídíà! Ẹ fi igbe ayọ̀ polongo rẹ̀! Ẹ kéde rẹ̀!+ Ẹ jẹ́ kó di mímọ̀ dé àwọn ìkángun ayé.+ Ẹ sọ pé: “Jèhófà ti tún Jékọ́bù ìránṣẹ́ rẹ̀ rà.+
3 Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé: “Ẹ tún ọ̀nà Jèhófà ṣe!*+ Ẹ la ọ̀nà tó tọ́ + gba inú aṣálẹ̀ fún Ọlọ́run wa.+
20 Ẹ jáde kúrò ní Bábílónì!+Ẹ sá kúrò lọ́dọ̀ àwọn ará Kálídíà! Ẹ fi igbe ayọ̀ polongo rẹ̀! Ẹ kéde rẹ̀!+ Ẹ jẹ́ kó di mímọ̀ dé àwọn ìkángun ayé.+ Ẹ sọ pé: “Jèhófà ti tún Jékọ́bù ìránṣẹ́ rẹ̀ rà.+