Àìsáyà 49:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run, sì máa yọ̀, ìwọ ayé.+ Kí inú àwọn òkè dùn, kí wọ́n sì kígbe ayọ̀.+ Torí Jèhófà ti tu àwọn èèyàn rẹ̀ nínú,+Ó sì ń ṣàánú àwọn èèyàn rẹ̀ tí ìyà ń jẹ.+
13 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run, sì máa yọ̀, ìwọ ayé.+ Kí inú àwọn òkè dùn, kí wọ́n sì kígbe ayọ̀.+ Torí Jèhófà ti tu àwọn èèyàn rẹ̀ nínú,+Ó sì ń ṣàánú àwọn èèyàn rẹ̀ tí ìyà ń jẹ.+