-
Jeremáyà 44:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Àṣẹ́kù Júdà tí wọ́n lọ ń gbé ní ilẹ̀ Íjíbítì kò ní lè sá àsálà tàbí kí wọ́n yè bọ́ láti pa dà sí ilẹ̀ Júdà. Á wù wọ́n* pé kí wọ́n pa dà, kí wọ́n sì máa gbé ibẹ̀, àmọ́ wọn ò ní lè pa dà, àyàfi àwọn díẹ̀ tó máa sá àsálà.’”
-