Diutarónómì 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó sì kéde májẹ̀mú rẹ̀ fún yín,+ èyí tó pa láṣẹ fún yín pé kí ẹ máa pa mọ́, ìyẹn Òfin Mẹ́wàá.*+ Lẹ́yìn náà, ó kọ ọ́ sórí wàláà òkúta méjì.+ Jeremáyà 14:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nítorí orúkọ rẹ, má kọ̀ wá sílẹ̀;+Má ṣe fojú àbùkù wo ìtẹ́ ògo rẹ. Rántí, má sì da májẹ̀mú tí o bá wa dá.+
13 Ó sì kéde májẹ̀mú rẹ̀ fún yín,+ èyí tó pa láṣẹ fún yín pé kí ẹ máa pa mọ́, ìyẹn Òfin Mẹ́wàá.*+ Lẹ́yìn náà, ó kọ ọ́ sórí wàláà òkúta méjì.+
21 Nítorí orúkọ rẹ, má kọ̀ wá sílẹ̀;+Má ṣe fojú àbùkù wo ìtẹ́ ògo rẹ. Rántí, má sì da májẹ̀mú tí o bá wa dá.+