28 Ó sì wà níbẹ̀ pẹ̀lú Jèhófà fún ogójì (40) ọ̀sán àti ogójì (40) òru. Kò jẹun rárá, kò sì mu omi.+ Ó sì kọ ọ̀rọ̀ májẹ̀mú náà sára àwọn wàláà náà, Òfin Mẹ́wàá.*+
4 Ó wá kọ àwọn ọ̀rọ̀ tó ti kọ tẹ́lẹ̀ sára àwọn wàláà náà,+ ìyẹn Òfin Mẹ́wàá,*+ tí Jèhófà bá yín sọ lórí òkè náà látinú iná,+ ní ọjọ́ tí ẹ pé jọ;*+ Jèhófà sì kó o fún mi.