-
Léfítíkù 26:41, 42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 Èmi náà sì kẹ̀yìn sí wọn,+ torí mo mú wọn wá sí ilẹ̀ àwọn ọ̀tá wọn.+
“‘Bóyá nígbà yẹn, wọ́n á rẹ ọkàn wọn tí wọn ò kọ nílà* wálẹ̀,+ wọ́n á sì wá jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn. 42 Màá sì rántí májẹ̀mú tí mo bá Jékọ́bù dá+ àti májẹ̀mú tí mo bá Ísákì dá,+ màá rántí májẹ̀mú tí mo bá Ábúráhámù dá,+ màá sì rántí ilẹ̀ náà.
-