Diutarónómì 30:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa wẹ ọkàn rẹ mọ́* àti ọkàn ọmọ+ rẹ, kí o lè fi gbogbo ọkàn rẹ àti gbogbo ara* rẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ, kí o sì máa wà láàyè.+ Jeremáyà 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ kọ ara yín nílà* fún Jèhófà,Ẹ sì kọlà fún* ọkàn yín,+Ẹ̀yin èèyàn Júdà àti ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé Jerúsálẹ́mù,Kí ìbínú mi má bàa ru jáde bí ináKí ó sì máa jó, tí kò fi ní sí ẹni tó lè pa á,Nítorí ìwà ibi yín.”+ Ìṣe 7:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 “Ẹ̀yin olóríkunkun àti aláìkọlà* ọkàn àti etí, gbogbo ìgbà lẹ̀ ń ta ko ẹ̀mí mímọ́; bí àwọn baba ńlá yín ti ṣe náà lẹ̀ ń ṣe.+
6 Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa wẹ ọkàn rẹ mọ́* àti ọkàn ọmọ+ rẹ, kí o lè fi gbogbo ọkàn rẹ àti gbogbo ara* rẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ, kí o sì máa wà láàyè.+
4 Ẹ kọ ara yín nílà* fún Jèhófà,Ẹ sì kọlà fún* ọkàn yín,+Ẹ̀yin èèyàn Júdà àti ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé Jerúsálẹ́mù,Kí ìbínú mi má bàa ru jáde bí ináKí ó sì máa jó, tí kò fi ní sí ẹni tó lè pa á,Nítorí ìwà ibi yín.”+
51 “Ẹ̀yin olóríkunkun àti aláìkọlà* ọkàn àti etí, gbogbo ìgbà lẹ̀ ń ta ko ẹ̀mí mímọ́; bí àwọn baba ńlá yín ti ṣe náà lẹ̀ ń ṣe.+