Ẹ́sítà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 lákòókò yẹn, Ọba Ahasuérúsì wà lórí ìtẹ́ rẹ̀ ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* Ẹ́sítà 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àwọn asáréjíṣẹ́ náà jáde lọ kíákíá+ bí ọba ṣe pa á láṣẹ; wọ́n gbé òfin náà jáde ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá.* Ọba àti Hámánì wá jókòó láti mutí, àmọ́ ìlú Ṣúṣánì* wà nínú ìdàrúdàpọ̀. Dáníẹ́lì 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Mo rí ìran náà, bí mo sì ṣe ń wò ó, mo wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* tó wà ní ìpínlẹ̀* Élámù;+ mo rí ìran náà, mo sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ipadò Úláì.
15 Àwọn asáréjíṣẹ́ náà jáde lọ kíákíá+ bí ọba ṣe pa á láṣẹ; wọ́n gbé òfin náà jáde ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá.* Ọba àti Hámánì wá jókòó láti mutí, àmọ́ ìlú Ṣúṣánì* wà nínú ìdàrúdàpọ̀.
2 Mo rí ìran náà, bí mo sì ṣe ń wò ó, mo wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* tó wà ní ìpínlẹ̀* Élámù;+ mo rí ìran náà, mo sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ipadò Úláì.