Ẹ́sítà 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Lẹ́yìn èyí, Ọba Ahasuérúsì gbé Hámánì+ ọmọ Hamédátà ọmọ Ágágì+ ga, ó sì gbé ìtẹ́ rẹ̀ ga ju ti gbogbo àwọn ìjòyè yòókù tí wọ́n jọ wà.+ Ẹ́sítà 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọba wá bọ́ òrùka àṣẹ+ rẹ̀ tó gbà lọ́wọ́ Hámánì, ó sì fún Módékáì. Ẹ́sítà sì fi Módékáì ṣe olórí ilé Hámánì.+
3 Lẹ́yìn èyí, Ọba Ahasuérúsì gbé Hámánì+ ọmọ Hamédátà ọmọ Ágágì+ ga, ó sì gbé ìtẹ́ rẹ̀ ga ju ti gbogbo àwọn ìjòyè yòókù tí wọ́n jọ wà.+
2 Ọba wá bọ́ òrùka àṣẹ+ rẹ̀ tó gbà lọ́wọ́ Hámánì, ó sì fún Módékáì. Ẹ́sítà sì fi Módékáì ṣe olórí ilé Hámánì.+